Jẹ́nẹ́sísì 24:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Lẹ́yìn tí Sérà ìyàwó ọ̀gá mi darúgbó,+ ó bí ọmọkùnrin kan fún ọ̀gá mi, ọmọ yìí ni yóò sì jogún gbogbo ohun tí ọ̀gá mi ní.+
36 Lẹ́yìn tí Sérà ìyàwó ọ̀gá mi darúgbó,+ ó bí ọmọkùnrin kan fún ọ̀gá mi, ọmọ yìí ni yóò sì jogún gbogbo ohun tí ọ̀gá mi ní.+