Jẹ́nẹ́sísì 16:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Áńgẹ́lì Jèhófà wá sọ pé: “Èmi yóò mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ gan-an débi pé wọn ò ní lè kà wọ́n.”+ 11 Áńgẹ́lì Jèhófà fi kún un pé: “O ti lóyún, wàá sì bí ọmọkùnrin kan, kí o pe orúkọ rẹ̀ ní Íṣímáẹ́lì,* torí Jèhófà ti gbọ́ nípa ìyà tó ń jẹ ọ́.
10 Áńgẹ́lì Jèhófà wá sọ pé: “Èmi yóò mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ gan-an débi pé wọn ò ní lè kà wọ́n.”+ 11 Áńgẹ́lì Jèhófà fi kún un pé: “O ti lóyún, wàá sì bí ọmọkùnrin kan, kí o pe orúkọ rẹ̀ ní Íṣímáẹ́lì,* torí Jèhófà ti gbọ́ nípa ìyà tó ń jẹ ọ́.