Jẹ́nẹ́sísì 22:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó wá sọ pé: “Jọ̀ọ́, mú ọmọ rẹ, ọmọ rẹ kan ṣoṣo tí o nífẹ̀ẹ́ gidigidi,+ ìyẹn Ísákì,+ kí o sì lọ sí ilẹ̀ Moráyà,+ kí o fi rú ẹbọ sísun níbẹ̀ lórí ọ̀kan nínú àwọn òkè tí màá fi hàn ọ́.” Mátíù 1:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ìwé ìtàn* nípa Jésù Kristi,* ọmọ Dáfídì,+ ọmọ Ábúráhámù:+ 2 Ábúráhámù bí Ísákì;+Ísákì bí Jékọ́bù;+Jékọ́bù bí Júdà+ àti àwọn arákùnrin rẹ̀;
2 Ó wá sọ pé: “Jọ̀ọ́, mú ọmọ rẹ, ọmọ rẹ kan ṣoṣo tí o nífẹ̀ẹ́ gidigidi,+ ìyẹn Ísákì,+ kí o sì lọ sí ilẹ̀ Moráyà,+ kí o fi rú ẹbọ sísun níbẹ̀ lórí ọ̀kan nínú àwọn òkè tí màá fi hàn ọ́.”
1 Ìwé ìtàn* nípa Jésù Kristi,* ọmọ Dáfídì,+ ọmọ Ábúráhámù:+ 2 Ábúráhámù bí Ísákì;+Ísákì bí Jékọ́bù;+Jékọ́bù bí Júdà+ àti àwọn arákùnrin rẹ̀;