-
Jẹ́nẹ́sísì 27:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àmọ́ Rèbékà ń gbọ́ ohun tí Ísákì ń bá Ísọ̀ ọmọ rẹ̀ sọ. Ísọ̀ sì lọ sínú igbó kó lè pa ẹran ìgbẹ́ wálé.+