Jẹ́nẹ́sísì 25:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Bí àwọn ọmọ náà ṣe ń dàgbà, Ísọ̀ di ọdẹ+ tó já fáfá, inú igbó ló sábà máa ń lọ, àmọ́ Jékọ́bù jẹ́ aláìlẹ́bi, inú àgọ́+ ló máa ń wà.
27 Bí àwọn ọmọ náà ṣe ń dàgbà, Ísọ̀ di ọdẹ+ tó já fáfá, inú igbó ló sábà máa ń lọ, àmọ́ Jékọ́bù jẹ́ aláìlẹ́bi, inú àgọ́+ ló máa ń wà.