ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 17:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 O ò ní jẹ́ Ábúrámù* mọ́; orúkọ rẹ yóò di Ábúráhámù,* torí màá mú kí o di bàbá ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè. 6 Màá mú kí o bímọ tó pọ̀ gan-an, màá mú kí o di àwọn orílẹ̀-èdè, àwọn ọba yóò sì tinú rẹ jáde.+

  • Jẹ́nẹ́sísì 28:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Torí náà, Ísákì pe Jékọ́bù, ó súre fún un, ó sì pàṣẹ fún un pé: “O ò gbọ́dọ̀ fẹ́ ìyàwó láàárín àwọn ọmọ Kénáánì!+

  • Jẹ́nẹ́sísì 28:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ọlọ́run Olódùmarè yóò bù kún ọ, yóò mú kí o bímọ tó pọ̀, yóò mú kí o pọ̀ gan-an, ó sì dájú pé ìwọ yóò di àwùjọ àwọn èèyàn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́