-
Jẹ́nẹ́sísì 27:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ni ìyá rẹ̀ bá sọ fún un pé: “Ọmọ mi, kí ègún tó yẹ kó wá sórí rẹ kọjá sórí mi. Ṣáà lọ ṣe ohun tí mo sọ fún ọ, lọ bá mi mú wọn wá.”+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 27:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Torí náà, ọmọ mi, ṣe ohun tí mo bá sọ fún ọ. Gbéra, kí o sì sá lọ sọ́dọ̀ Lábánì arákùnrin mi ní Háránì.+
-