-
Jẹ́nẹ́sísì 27:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ọmọ mi, fetí sílẹ̀ dáadáa, kí o sì ṣe ohun tí mo fẹ́ sọ fún ọ.+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 27:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Torí náà, ọmọ mi, ṣe ohun tí mo bá sọ fún ọ. Gbéra, kí o sì sá lọ sọ́dọ̀ Lábánì arákùnrin mi ní Háránì.+
-