Jẹ́nẹ́sísì 27:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí náà, ní báyìí, jọ̀ọ́ lọ mú àwọn nǹkan tí o fi ń ṣọdẹ, mú apó rẹ àti ọfà* rẹ, kí o lọ sínú igbó, kí o sì pa ẹran ìgbẹ́ wá fún mi.+
3 Torí náà, ní báyìí, jọ̀ọ́ lọ mú àwọn nǹkan tí o fi ń ṣọdẹ, mú apó rẹ àti ọfà* rẹ, kí o lọ sínú igbó, kí o sì pa ẹran ìgbẹ́ wá fún mi.+