-
Jẹ́nẹ́sísì 25:32-34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Ísọ̀ dá a lóhùn pé: “Èmi tí mo ti fẹ́rẹ̀ẹ́ kú! Kí ni ogún ìbí fẹ́ dà fún mi?” 33 Jékọ́bù sọ pé: “Kọ́kọ́ búra fún mi!” Ló bá búra fún un, ó sì ta ogún ìbí rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àkọ́bí fún Jékọ́bù.+ 34 Jékọ́bù wá fún Ísọ̀ ní búrẹ́dì àti ọbẹ̀ ẹ̀wà lẹ́ńtìlì, ó jẹ, ó sì mu. Ó dìde, ó sì ń lọ. Bí Ísọ̀ ṣe fi hàn pé òun ò mọyì ogún ìbí rẹ̀ nìyẹn.
-