Jẹ́nẹ́sísì 12:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà wá fara han Ábúrámù, ó sì sọ pé: “Ọmọ* rẹ+ ni èmi yóò fún ní ilẹ̀ yìí.”+ Ó sì mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà, ẹni tó fara hàn án. Jẹ́nẹ́sísì 28:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Yóò bù kún ọ bó ṣe ṣèlérí fún Ábúráhámù,+ ìwọ àti àtọmọdọ́mọ* rẹ, kí ilẹ̀ tí ò ń gbé bí àjèjì, tí Ọlọ́run ti fún Ábúráhámù+ lè di ohun ìní rẹ.” Sáàmù 105:9-11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Májẹ̀mú tó bá Ábúráhámù dá+Àti ìbúra rẹ̀ fún Ísákì,+10 Èyí tó gbé kalẹ̀ bí ìlànà fún Jékọ́bùÀti bíi májẹ̀mú tó wà títí láé fún Ísírẹ́lì,11 Ó ní, “Màá fún ọ ní ilẹ̀ Kénáánì+Bí ogún tí a pín fún yín.”+
7 Jèhófà wá fara han Ábúrámù, ó sì sọ pé: “Ọmọ* rẹ+ ni èmi yóò fún ní ilẹ̀ yìí.”+ Ó sì mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà, ẹni tó fara hàn án.
4 Yóò bù kún ọ bó ṣe ṣèlérí fún Ábúráhámù,+ ìwọ àti àtọmọdọ́mọ* rẹ, kí ilẹ̀ tí ò ń gbé bí àjèjì, tí Ọlọ́run ti fún Ábúráhámù+ lè di ohun ìní rẹ.”
9 Májẹ̀mú tó bá Ábúráhámù dá+Àti ìbúra rẹ̀ fún Ísákì,+10 Èyí tó gbé kalẹ̀ bí ìlànà fún Jékọ́bùÀti bíi májẹ̀mú tó wà títí láé fún Ísírẹ́lì,11 Ó ní, “Màá fún ọ ní ilẹ̀ Kénáánì+Bí ogún tí a pín fún yín.”+