Jẹ́nẹ́sísì 34:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Àmọ́ ní ọjọ́ kẹta, nígbà tí wọ́n ṣì ń jẹ̀rora, àwọn ọmọ Jékọ́bù méjì, Síméónì àti Léfì tí wọ́n jẹ́ ẹ̀gbọ́n+ Dínà mú idà wọn, wọ́n yọ́ lọ sí ìlú náà, wọ́n sì pa gbogbo ọkùnrin.+ Jẹ́nẹ́sísì 49:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Tẹ̀gbọ́n-tàbúrò+ ni Síméónì àti Léfì. Ohun èlò ìwà ipá ni ohun ìjà wọn.+ 1 Kíróníkà 4:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àwọn ọmọ Síméónì+ ni Némúẹ́lì, Jámínì, Járíbù, Síírà àti Ṣéọ́lù.+
25 Àmọ́ ní ọjọ́ kẹta, nígbà tí wọ́n ṣì ń jẹ̀rora, àwọn ọmọ Jékọ́bù méjì, Síméónì àti Léfì tí wọ́n jẹ́ ẹ̀gbọ́n+ Dínà mú idà wọn, wọ́n yọ́ lọ sí ìlú náà, wọ́n sì pa gbogbo ọkùnrin.+