Lúùkù 1:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọjọ́ mélòó kan lẹ́yìn náà, Èlísábẹ́tì ìyàwó rẹ̀ lóyún, ó sì fi ara pa mọ́ fún oṣù márùn-ún, ó sọ pé: 25 “Ohun tí Jèhófà* ṣe sí mi ní àwọn ọjọ́ yìí nìyí. Ó ti yíjú sí mi kó lè mú ẹ̀gàn mi kúrò láàárín àwọn èèyàn.”+
24 Ọjọ́ mélòó kan lẹ́yìn náà, Èlísábẹ́tì ìyàwó rẹ̀ lóyún, ó sì fi ara pa mọ́ fún oṣù márùn-ún, ó sọ pé: 25 “Ohun tí Jèhófà* ṣe sí mi ní àwọn ọjọ́ yìí nìyí. Ó ti yíjú sí mi kó lè mú ẹ̀gàn mi kúrò láàárín àwọn èèyàn.”+