ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 30:22, 23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Níkẹyìn, Ọlọ́run rántí Réṣẹ́lì, Ọlọ́run fetí sí i, ó sì dá a lóhùn torí ó jẹ́ kó lóyún.*+ 23 Ó lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan. Ó wá sọ pé: “Ọlọ́run ti mú ẹ̀gàn+ mi kúrò!”

  • 1 Sámúẹ́lì 1:10, 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Inú Hánà bà jẹ́* gan-an, ó bẹ̀rẹ̀ sí í gbàdúrà sí Jèhófà,+ ó sì ń sunkún tẹ̀dùntẹ̀dùn. 11 Ó wá jẹ́ ẹ̀jẹ́ yìí pé: “Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, tí o bá bojú wo ìnira tó dé bá ìránṣẹ́ rẹ, tí o rántí mi, tí o kò gbàgbé ìránṣẹ́ rẹ, tí o sì fún ìránṣẹ́ rẹ ní ọmọ ọkùnrin,+ ṣe ni màá fi fún Jèhófà ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, abẹ kò sì ní kan orí rẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́