-
Jẹ́nẹ́sísì 31:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Tó bá sọ pé, ‘Àwọn aláwọ̀ tó-tò-tó ló máa jẹ́ èrè rẹ,’ ìgbà yẹn ni gbogbo ẹran á bí aláwọ̀ tó-tò-tó; àmọ́ tó bá sọ pé, ‘Àwọn abilà ló máa jẹ́ èrè rẹ,’ ìgbà yẹn ni gbogbo ẹran á bí abilà.+
-