Jẹ́nẹ́sísì 35:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nígbà tó yá, Jékọ́bù dé ibi tí Ísákì bàbá rẹ̀ wà ní Mámúrè,+ ní Kiriati-ábà, ìyẹn Hébúrónì, níbi tí Ábúráhámù àti Ísákì pẹ̀lú ti gbé rí bí àjèjì.+
27 Nígbà tó yá, Jékọ́bù dé ibi tí Ísákì bàbá rẹ̀ wà ní Mámúrè,+ ní Kiriati-ábà, ìyẹn Hébúrónì, níbi tí Ábúráhámù àti Ísákì pẹ̀lú ti gbé rí bí àjèjì.+