Jẹ́nẹ́sísì 31:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jékọ́bù wá dìde, ó sì gbé àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìyàwó rẹ̀ sórí àwọn ràkúnmí,+ 18 ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í da agbo ẹran rẹ̀ àti gbogbo ohun tí ó ti ní,+ àwọn ẹran ọ̀sìn tó wá di tirẹ̀ ní Padani-árámù, ó dà wọ́n lọ sọ́dọ̀ Ísákì bàbá rẹ̀ ní ilẹ̀ Kénáánì.+
17 Jékọ́bù wá dìde, ó sì gbé àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìyàwó rẹ̀ sórí àwọn ràkúnmí,+ 18 ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í da agbo ẹran rẹ̀ àti gbogbo ohun tí ó ti ní,+ àwọn ẹran ọ̀sìn tó wá di tirẹ̀ ní Padani-árámù, ó dà wọ́n lọ sọ́dọ̀ Ísákì bàbá rẹ̀ ní ilẹ̀ Kénáánì.+