-
Jẹ́nẹ́sísì 33:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àmọ́ Jékọ́bù sọ pé: “Jọ̀ọ́, má ṣe bẹ́ẹ̀. Tí mo bá rí ojúure rẹ, wàá gba ẹ̀bùn tí mo fún ọ lọ́wọ́ mi, torí kí n lè rí ojú rẹ ni mo ṣe mú un wá. Mo sì ti rí ojú rẹ, ó dà bí ìgbà tí mo rí ojú Ọlọ́run, torí o gbà mí tayọ̀tayọ̀.+
-