ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 32:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Mo bẹ̀ ọ́,+ gbà mí lọ́wọ́ Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n mi, torí ẹ̀rù rẹ̀ ń bà mí, ó lè wá gbógun ja èmi+ àti àwọn ọmọ mi pẹ̀lú àwọn ìyá wọn.

  • Jẹ́nẹ́sísì 32:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Kí ẹ tún sọ pé, ‘Jékọ́bù ìránṣẹ́ rẹ ń bọ̀ lẹ́yìn wa.’” Torí ó sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: ‘Tí mo bá kọ́kọ́ fi ẹ̀bùn ránṣẹ́,+ tí mo fi wá ojúure rẹ̀, tí mo bá wá rí òun fúnra rẹ̀, bóyá ó lè tẹ́wọ́ gbà mí.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́