Jẹ́nẹ́sísì 33:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ísọ̀ bi Jékọ́bù pé: “Kí ni gbogbo àwùjọ àwọn arìnrìn-àjò tí mo pàdé+ yìí wà fún?” Ó fèsì pé: “Kí n lè rí ojúure olúwa+ mi ni.”
8 Ísọ̀ bi Jékọ́bù pé: “Kí ni gbogbo àwùjọ àwọn arìnrìn-àjò tí mo pàdé+ yìí wà fún?” Ó fèsì pé: “Kí n lè rí ojúure olúwa+ mi ni.”