Hósíà 12:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó bá áńgẹ́lì kan jà títí ó fi borí. Ó sunkún, ó sì bẹ̀ ẹ́ pé kó ṣojúure sí òun.”+ Ọlọ́run rí i ní Bẹ́tẹ́lì, ibẹ̀ ni Ó sì ti bá wa sọ̀rọ̀,+
4 Ó bá áńgẹ́lì kan jà títí ó fi borí. Ó sunkún, ó sì bẹ̀ ẹ́ pé kó ṣojúure sí òun.”+ Ọlọ́run rí i ní Bẹ́tẹ́lì, ibẹ̀ ni Ó sì ti bá wa sọ̀rọ̀,+