Jẹ́nẹ́sísì 28:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wò ó! Jèhófà wà lókè rẹ̀, ó sì sọ pé: “Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run Ábúráhámù bàbá rẹ àti Ọlọ́run Ísákì.+ Ìwọ àti àtọmọdọ́mọ*+ rẹ ni màá fún ní ilẹ̀ tí o dùbúlẹ̀ sí yìí. Jẹ́nẹ́sísì 28:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó wá pe orúkọ ibẹ̀ ní Bẹ́tẹ́lì,* àmọ́ Lúsì+ ni ìlú náà ń jẹ́ tẹ́lẹ̀.
13 Wò ó! Jèhófà wà lókè rẹ̀, ó sì sọ pé: “Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run Ábúráhámù bàbá rẹ àti Ọlọ́run Ísákì.+ Ìwọ àti àtọmọdọ́mọ*+ rẹ ni màá fún ní ilẹ̀ tí o dùbúlẹ̀ sí yìí.