-
Jẹ́nẹ́sísì 32:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Nígbà tó yá, àwọn ìránṣẹ́ náà pa dà sọ́dọ̀ Jékọ́bù, wọ́n sì sọ fún un pé: “A rí Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n rẹ, ó sì ti ń bọ̀ wá pàdé rẹ+ pẹ̀lú ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ọkùnrin.”
-