Jẹ́nẹ́sísì 33:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó fi àwọn ìránṣẹ́bìnrin náà àti àwọn ọmọ wọn síwájú,+ Líà àti àwọn ọmọ rẹ̀ tẹ̀ lé wọn,+ Réṣẹ́lì+ àti Jósẹ́fù sì wà lẹ́yìn wọn.
2 Ó fi àwọn ìránṣẹ́bìnrin náà àti àwọn ọmọ wọn síwájú,+ Líà àti àwọn ọmọ rẹ̀ tẹ̀ lé wọn,+ Réṣẹ́lì+ àti Jósẹ́fù sì wà lẹ́yìn wọn.