-
Jẹ́nẹ́sísì 32:13-15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ó wá sun ibẹ̀ mọ́jú. Ó sì mú ẹ̀bùn fún Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n+ rẹ̀ látinú àwọn ohun ìní rẹ̀: 14 igba (200) abo ewúrẹ́, ogún (20) òbúkọ, igba (200) abo àgùntàn, ogún (20) àgbò, 15 ọgbọ̀n (30) ràkúnmí tó ń tọ́mọ, ogójì (40) màlúù, akọ màlúù mẹ́wàá, ogún (20) abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ àti akọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́+ mẹ́wàá tó ti dàgbà dáadáa.
-