7 Ní tèmi, nígbà tí mò ń bọ̀ láti Pádánì, Réṣẹ́lì kú+ lẹ́gbẹ̀ẹ́ mi nílẹ̀ Kénáánì, nígbà tí ọ̀nà ṣì jìn sí Éfúrátì.+ Mo sì sin ín níbẹ̀ lójú ọ̀nà Éfúrátì, ìyẹn Bẹ́tílẹ́hẹ́mù.”+
6 ‘Ìwọ Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti ilẹ̀ Júdà, lọ́nàkọnà, ìwọ kọ́ ni ìlú tó rẹlẹ̀ jù lára àwọn gómìnà Júdà, torí inú rẹ ni alákòóso ti máa jáde wá, ẹni tó máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.’”+