1 Sámúẹ́lì 17:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Dáfídì jẹ́ ọmọ Jésè ará Éfúrátà+ láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ ti Júdà. Jésè+ ní ọmọkùnrin mẹ́jọ,+ ó sì ti darúgbó gan-an ní ayé ìgbà Sọ́ọ̀lù. Mátíù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 ‘Ìwọ Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti ilẹ̀ Júdà, lọ́nàkọnà, ìwọ kọ́ ni ìlú tó rẹlẹ̀ jù lára àwọn gómìnà Júdà, torí inú rẹ ni alákòóso ti máa jáde wá, ẹni tó máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.’”+
12 Dáfídì jẹ́ ọmọ Jésè ará Éfúrátà+ láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ ti Júdà. Jésè+ ní ọmọkùnrin mẹ́jọ,+ ó sì ti darúgbó gan-an ní ayé ìgbà Sọ́ọ̀lù.
6 ‘Ìwọ Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti ilẹ̀ Júdà, lọ́nàkọnà, ìwọ kọ́ ni ìlú tó rẹlẹ̀ jù lára àwọn gómìnà Júdà, torí inú rẹ ni alákòóso ti máa jáde wá, ẹni tó máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.’”+