12 Séírì ni àwọn Hórì+ ń gbé tẹ́lẹ̀, àmọ́ àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀ lé wọn kúrò, wọ́n pa wọ́n run, wọ́n sì wá ń gbé ilẹ̀ wọn,+ ohun tí Ísírẹ́lì máa ṣe sí ilẹ̀ tó jẹ́ tiwọn nìyẹn, èyí tó dájú pé Jèhófà máa fún wọn.)
22 Ohun tó ṣe fún àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀ tí wọ́n ń gbé ní Séírì+ báyìí nìyẹn, nígbà tó pa àwọn Hórì+ run níwájú wọn, kí wọ́n lè lé wọn kúrò, kí wọ́n sì máa gbé ilẹ̀ wọn títí di òní yìí.