Jẹ́nẹ́sísì 14:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 àwọn Hórì+ ní òkè Séírì+ tó jẹ́ tiwọn, títí dé Eli-páránì, tó wà ní aginjù. Jẹ́nẹ́sísì 36:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àwọn ọmọ Séírì ọmọ Hórì tí wọ́n ń gbé ilẹ̀+ náà nìyí: Lótánì, Ṣóbálì, Síbéónì, Ánáhì,+