Jẹ́nẹ́sísì 36:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ísọ̀ fẹ́ ìyàwó láàárín àwọn ọmọ Kénáánì: Ádà+ ọmọ Élónì ọmọ Hétì;+ Oholibámà+ ọmọ Ánáhì, ọmọ ọmọ Síbéónì ọmọ Hífì;
2 Ísọ̀ fẹ́ ìyàwó láàárín àwọn ọmọ Kénáánì: Ádà+ ọmọ Élónì ọmọ Hétì;+ Oholibámà+ ọmọ Ánáhì, ọmọ ọmọ Síbéónì ọmọ Hífì;