-
Jẹ́nẹ́sísì 30:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Lẹ́yìn tí Réṣẹ́lì bí Jósẹ́fù, Jékọ́bù sọ fún Lábánì lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ pé: “Jẹ́ kí n máa lọ, kí n lè pa dà síbi tí mo ti wá àti sí ilẹ̀+ mi.
-