Jẹ́nẹ́sísì 25:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìtàn Íṣímáẹ́lì+ ọmọ Ábúráhámù nìyí, ẹni tí Hágárì+ ọmọ ilẹ̀ Íjíbítì tó jẹ́ ìránṣẹ́ Sérà bí fún Ábúráhámù.
12 Ìtàn Íṣímáẹ́lì+ ọmọ Ábúráhámù nìyí, ẹni tí Hágárì+ ọmọ ilẹ̀ Íjíbítì tó jẹ́ ìránṣẹ́ Sérà bí fún Ábúráhámù.