-
Jẹ́nẹ́sísì 38:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Ó bi í pé: “Kí ni kí n fi ṣe ìdúró fún ọ?” Obìnrin náà fèsì pé: “Òrùka èdìdì+ rẹ, okùn rẹ àti ọ̀pá ọwọ́ rẹ.” Ló bá kó o fún un, ó sì bá a lò pọ̀, obìnrin náà sì lóyún fún un.
-