Jẹ́nẹ́sísì 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ádámù pé ẹni àádóje (130) ọdún, ó wá bí ọmọkùnrin kan tó jọ ọ́, tó jẹ́ àwòrán rẹ̀, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Sẹ́ẹ̀tì.+ 1 Kíróníkà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ádámù,Sẹ́ẹ̀tì,+Énọ́ṣì,
3 Ádámù pé ẹni àádóje (130) ọdún, ó wá bí ọmọkùnrin kan tó jọ ọ́, tó jẹ́ àwòrán rẹ̀, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Sẹ́ẹ̀tì.+