Jẹ́nẹ́sísì 4:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ádámù tún bá ìyàwó rẹ̀ ní àṣepọ̀, ó sì bí ọmọkùnrin kan. Ó pe orúkọ rẹ̀ ní Sẹ́ẹ̀tì*+ torí ó sọ pé: “Ọlọ́run ti fi ọmọ* míì rọ́pò Ébẹ́lì fún mi, torí Kéènì pa á.”+
25 Ádámù tún bá ìyàwó rẹ̀ ní àṣepọ̀, ó sì bí ọmọkùnrin kan. Ó pe orúkọ rẹ̀ ní Sẹ́ẹ̀tì*+ torí ó sọ pé: “Ọlọ́run ti fi ọmọ* míì rọ́pò Ébẹ́lì fún mi, torí Kéènì pa á.”+