Jẹ́nẹ́sísì 46:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn ọmọ Júdà+ ni Éérì, Ónánì, Ṣélà,+ Pérésì+ àti Síírà.+ Àmọ́ Éérì àti Ónánì kú ní ilẹ̀ Kénáánì.+ Àwọn ọmọ Pérésì ni Hésírónì àti Hámúlù.+ Rúùtù 4:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kí ọmọ tí Jèhófà yóò fún ọ látọ̀dọ̀ obìnrin yìí+ mú kí ilé rẹ dà bí ilé Pérésì,+ tí Támárì bí fún Júdà.” 1 Kíróníkà 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Támárì+ ìyàwó ọmọ Júdà bí Pérésì+ àti Síírà fún un. Gbogbo àwọn ọmọ Júdà jẹ́ márùn-ún. Lúùkù 3:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọJósẹ́fù,+ọmọ Hélì, Lúùkù 3:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 ọmọ Ámínádábù,ọmọ Áánì,ọmọ Hésírónì,ọmọ Pérésì,+ọmọ Júdà,+ Yorùbá Publications (1987-2025) Jáde Wọlé Yorùbá Fi Ráńṣẹ́ Èyí tí mo fẹ́ràn jù Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania Àdéhùn Nípa Lílò Òfin Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ JW.ORG Wọlé Fi Ráńṣẹ́ Fi Ráńṣẹ́ Lórí Email
12 Àwọn ọmọ Júdà+ ni Éérì, Ónánì, Ṣélà,+ Pérésì+ àti Síírà.+ Àmọ́ Éérì àti Ónánì kú ní ilẹ̀ Kénáánì.+ Àwọn ọmọ Pérésì ni Hésírónì àti Hámúlù.+
12 Kí ọmọ tí Jèhófà yóò fún ọ látọ̀dọ̀ obìnrin yìí+ mú kí ilé rẹ dà bí ilé Pérésì,+ tí Támárì bí fún Júdà.”
23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọJósẹ́fù,+ọmọ Hélì, Lúùkù 3:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 ọmọ Ámínádábù,ọmọ Áánì,ọmọ Hésírónì,ọmọ Pérésì,+ọmọ Júdà,+