Ẹ́kísódù 39:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Wọ́n fi fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù àti òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò+ hun àwọn aṣọ lọ́nà tó dáa láti máa fi ṣiṣẹ́ ní ibi mímọ́. Wọ́n ṣe àwọn aṣọ mímọ́ ti Áárónì,+ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.
39 Wọ́n fi fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù àti òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò+ hun àwọn aṣọ lọ́nà tó dáa láti máa fi ṣiṣẹ́ ní ibi mímọ́. Wọ́n ṣe àwọn aṣọ mímọ́ ti Áárónì,+ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.