ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 26:26-28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 “Kí o fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe àwọn ọ̀pá gbọọrọ, ọ̀pá gbọọrọ márùn-ún fún àwọn férémù tó wà ní ẹ̀gbẹ́ kan àgọ́ ìjọsìn náà,+ 27 ọ̀pá gbọọrọ márùn-ún fún àwọn férémù tó wà ní ẹ̀gbẹ́ kejì àgọ́ ìjọsìn náà àti ọ̀pá gbọọrọ márùn-ún fún àwọn férémù tó wà ní ẹ̀gbẹ́ àgọ́ ìjọsìn náà lápá ìwọ̀ oòrùn, ní ẹ̀yìn. 28 Kí ọ̀pá gbọọrọ tó wà láàárín gba àárín àwọn férémù náà kọjá láti ìkángun dé ìkángun.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́