-
Ẹ́kísódù 36:31-33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Ó wá fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe àwọn ọ̀pá gbọọrọ, ọ̀pá gbọọrọ márùn-ún fún àwọn férémù tó wà ní ẹ̀gbẹ́ kan àgọ́ ìjọsìn náà+ 32 àti ọ̀pá gbọọrọ márùn-ún fún àwọn férémù tó wà ní ẹ̀gbẹ́ kejì àgọ́ ìjọsìn náà àti ọ̀pá gbọọrọ márùn-ún fún férémù ọwọ́ ẹ̀yìn àgọ́ ìjọsìn náà lápá ìwọ̀ oòrùn. 33 Ó ṣe ọ̀pá gbọọrọ sí àárín, èyí tó gba àárín àwọn férémù náà kọjá láti ìkángun kan sí èkejì.
-