Ẹ́kísódù 40:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Gbé àpótí Ẹ̀rí sínú rẹ̀,+ kí o sì ta aṣọ ìdábùú bo ibi tí Àpótí náà wà.+ Nọ́ńbà 10:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Lẹ́yìn náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í kúrò ní òkè Jèhófà,+ wọ́n rin ìrìn ọjọ́ mẹ́ta, àpótí+ májẹ̀mú Jèhófà sì ń lọ níwájú wọn ní ọjọ́ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta láti wá ibi ìsinmi fún wọn.+
33 Lẹ́yìn náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í kúrò ní òkè Jèhófà,+ wọ́n rin ìrìn ọjọ́ mẹ́ta, àpótí+ májẹ̀mú Jèhófà sì ń lọ níwájú wọn ní ọjọ́ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta láti wá ibi ìsinmi fún wọn.+