-
Jóṣúà 3:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 wọ́n sì pàṣẹ fún àwọn èèyàn náà pé: “Gbàrà tí ẹ bá rí i tí àwọn ọmọ Léfì tí wọ́n jẹ́ àlùfáà+ gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà Ọlọ́run yín, kí ẹ gbéra láti àyè yín, kí ẹ sì tẹ̀ lé e. 4 Àmọ́ kí ẹ fi àyè tí ó tó nǹkan bí ẹgbẹ̀rún méjì (2,000) ìgbọ̀nwọ́* sílẹ̀ láàárín ẹ̀yin àti àpótí náà; ẹ má ṣe sún mọ́ ọn rárá, kí ẹ lè mọ ọ̀nà tí ẹ máa gbà, torí pé ẹ ò gba ọ̀nà yìí rí.”
-