ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 25:10-15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Kí wọ́n fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe àpótí, kí gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́* méjì ààbọ̀, kí fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀, kí gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+ 11 Kí o wá fi ògidì wúrà bò ó.+ Kí o fi bò ó nínú àti níta, kí o sì ṣe ìgbátí wúrà sí i* yí ká.+ 12 Kí o fi wúrà rọ òrùka mẹ́rin fún un, kí o sì fi wọ́n síbi òkè ẹsẹ̀ rẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin, òrùka méjì ní ẹ̀gbẹ́ kan àti òrùka méjì ní ẹ̀gbẹ́ kejì. 13 Kí o fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe àwọn ọ̀pá, kí o sì fi wúrà bò wọ́n.+ 14 O máa ki àwọn ọ̀pá náà bọ inú àwọn òrùka tó wà ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì Àpótí náà, kí ẹ lè máa fi gbé Àpótí náà. 15 Inú àwọn òrùka Àpótí náà ni kí àwọn ọ̀pá náà máa wà; ẹ má ṣe yọ wọ́n kúrò níbẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́