ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 37:1-5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Bẹ́sálẹ́lì+ wá fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe Àpótí.+ Gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́* méjì ààbọ̀, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀.+ 2 Ó fi ògidì wúrà bò ó nínú àti níta, ó sì ṣe ìgbátí wúrà sí i* yí ká.+ 3 Lẹ́yìn náà, ó fi wúrà rọ òrùka mẹ́rin fún un, ó fi síbi òkè ẹsẹ̀ rẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin, òrùka méjì ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ kan àti òrùka méjì ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ kejì. 4 Ó wá fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe àwọn ọ̀pá, ó sì fi wúrà bò wọ́n.+ 5 Ó ki àwọn ọ̀pá náà bọnú àwọn òrùka tó wà ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì Àpótí náà, láti máa fi gbé Àpótí náà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́