-
Ẹ́kísódù 40:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Ó gbé ọ̀pá fìtílà+ sínú àgọ́ ìpàdé níwájú tábìlì náà, ní apá gúúsù àgọ́ ìjọsìn náà.
-
-
Léfítíkù 24:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Kó máa to àwọn fìtílà náà sórí ọ̀pá fìtílà+ tí wọ́n fi ògidì wúrà ṣe, èyí tó wà níwájú Jèhófà nígbà gbogbo.
-
-
2 Kíróníkà 13:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Wọ́n ń mú àwọn ẹbọ sísun rú èéfín sí Jèhófà ní àràárọ̀ àti ní ìrọ̀lẹ́-ìrọ̀lẹ́+ pẹ̀lú tùràrí onílọ́fínńdà,+ àwọn búrẹ́dì onípele*+ sì wà lórí tábìlì ògidì wúrà, wọ́n máa ń tan ọ̀pá fìtílà wúrà+ àti àwọn fìtílà rẹ̀ ní alaalẹ́,+ nítorí pé à ń ṣe ojúṣe wa fún Jèhófà Ọlọ́run wa; àmọ́ ẹ̀yin ti fi í sílẹ̀.
-