31 “Kí o fi ògidì wúrà ṣe ọ̀pá fìtílà.+ Kí ọ̀pá fìtílà náà jẹ́ iṣẹ́ ọnà tí o fi òòlù ṣe. Kí ìsàlẹ̀ rẹ̀, ọ̀pá rẹ̀, àwọn ẹ̀ka rẹ̀, àwọn iṣẹ́ ọnà rẹ̀, àwọn kókó rubutu rẹ̀ àti àwọn ìtànná rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan ṣoṣo.+
33 Lẹ́yìn náà, wọ́n gbé àgọ́ ìjọsìn+ náà wá sọ́dọ̀ Mósè, àgọ́ náà+ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀: àwọn ìkọ́ rẹ̀,+ àwọn férémù rẹ̀,+ àwọn ọ̀pá gbọọrọ rẹ̀+ àti àwọn òpó rẹ̀ àti àwọn ìtẹ́lẹ̀ oníhò rẹ̀;+