Ẹ́kísódù 30:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Kí o wá fi ṣe òróró àfiyanni mímọ́; kí o ro àwọn èròjà náà pọ̀ dáadáa.*+ Òróró àfiyanni mímọ́ ni yóò jẹ́. Ẹ́kísódù 30:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ẹnikẹ́ni tó bá ṣe òróró ìpara tó dà bíi rẹ̀ tàbí tó fi pa ẹni tí kò tọ́ sí* lára, kí ẹ pa ẹni náà, kí ẹ lè mú un kúrò nínú àwọn èèyàn rẹ̀.’”+ Ẹ́kísódù 40:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lẹ́yìn náà, kí o gbé òróró àfiyanni,+ kí o fòróró yan àgọ́ ìjọsìn náà àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀,+ kí o sì ya àgọ́ náà àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ sí mímọ́, kó lè di ohun mímọ́.
25 Kí o wá fi ṣe òróró àfiyanni mímọ́; kí o ro àwọn èròjà náà pọ̀ dáadáa.*+ Òróró àfiyanni mímọ́ ni yóò jẹ́.
33 Ẹnikẹ́ni tó bá ṣe òróró ìpara tó dà bíi rẹ̀ tàbí tó fi pa ẹni tí kò tọ́ sí* lára, kí ẹ pa ẹni náà, kí ẹ lè mú un kúrò nínú àwọn èèyàn rẹ̀.’”+
9 Lẹ́yìn náà, kí o gbé òróró àfiyanni,+ kí o fòróró yan àgọ́ ìjọsìn náà àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀,+ kí o sì ya àgọ́ náà àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ sí mímọ́, kó lè di ohun mímọ́.