Ẹ́kísódù 30:37, 38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe tùràrí tó ní irú èròjà yìí fún ìlò ara yín.+ Kí ẹ kà á sí ohun mímọ́ fún Jèhófà. 38 Tí ẹnikẹ́ni bá ṣe ohun tó jọ ọ́ láti máa gbádùn òórùn rẹ̀, ṣe ni kí ẹ pa ẹni náà, kí ẹ lè mú un kúrò nínú àwọn èèyàn rẹ̀.
37 Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe tùràrí tó ní irú èròjà yìí fún ìlò ara yín.+ Kí ẹ kà á sí ohun mímọ́ fún Jèhófà. 38 Tí ẹnikẹ́ni bá ṣe ohun tó jọ ọ́ láti máa gbádùn òórùn rẹ̀, ṣe ni kí ẹ pa ẹni náà, kí ẹ lè mú un kúrò nínú àwọn èèyàn rẹ̀.