-
Ẹ́kísódù 25:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Kí o gbé Ẹ̀rí tí èmi yóò fún ọ sínú Àpótí náà.+
-
-
Nọ́ńbà 17:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Mósè wá kó àwọn ọ̀pá náà síwájú Jèhófà nínú àgọ́ Ẹ̀rí.
-