Léfítíkù 8:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó wá wọ aṣọ ìgbàyà+ fún un, ó sì fi Úrímù àti Túmímù+ sí aṣọ ìgbàyà náà.