- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 36:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        24 Ó wá fi fàdákà ṣe ogójì (40) ìtẹ́lẹ̀ oníhò sábẹ́ ogún (20) férémù náà, ìtẹ́lẹ̀ méjì tó ní ihò sábẹ́ férémù kan kí ìtẹ̀bọ̀ méjì férémù náà lè wọnú rẹ̀, ó sì ṣe ìtẹ́lẹ̀ méjì tó ní ihò sábẹ́ ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn férémù yòókù, kí ìtẹ̀bọ̀ méjì férémù náà lè wọnú rẹ̀.+ 
 
-